Wikidata:Main Page/Welcome/yo

This page is a translated version of the page Wikidata:Main Page/Welcome and the translation is 100% complete.

Wikidata jẹ ipilẹ ìmọ ọfẹ ati ṣiṣi ti o le ka ati ṣatunkọ nipasẹ awọn eniyan ati awọn ẹrọ.

Wikidata n ṣiṣẹ bi fonran ipamon gbogbo 'gbo fun data alatunto wikimedia ti nse amugba legbe re, pẹlu Wikipedia, Wikivoyage, Wiktionary, Wikisource, ati awọn miiran.

Wikidata tun pese atilẹyin si ọpọlọpọ awọn aaye ati awọn iṣẹ miiran ju awọn iṣẹ akanṣe Wikimedia lọ! Àkóónú Wikidata jẹ́ tó wà lábẹ́ ìwé àṣẹ ọ̀fẹ́, tí a fi ránṣẹ́ sí ilẹ̀ ní lílo àwọn àwòkẹ́kọ̀ọ́ àfidíwọ̀n, àti ó le ṣe ìsopọ̀ mọ́ àwọn ìtòlẹ́sẹẹsẹ dátà míràn lórí wẹ́ẹ̀bù ìsopọ̀.